Deutarónómì 29:20 BMY

20 Olúwa kì yóò ní ìfẹ́ sí àti dáríjìí; ìbínú àti ìtara rẹ̀ yóò jó ọkùnrin náà. Gbogbo àwọn ègún tí a kọ sínú ìwé yìí yóò wá sórí i rẹ̀, Olúwa yóò sì yọ orúkọ rẹ̀ kúrò lábẹ́ ọ̀run.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:20 ni o tọ