Deutarónómì 29:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n títí di àsìkò yìí Olúwa kò fi ọkàn ìmòye tàbí ojú tí ó ń rí tàbí etí tí ó n gbọ́ fún ọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:4 ni o tọ