Deutarónómì 3:1 BMY

1 Lẹ́yìn èyí ní a yípadà tí a sì kọrí sí ọ̀nà tí ó lọ sí Báṣánì, Ógù ọba Báṣánì àti gbogbo jagunjagun rẹ̀ ṣígun wá pàdé wa ní Édíréì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:1 ni o tọ