Deutarónómì 3:2 BMY

2 Olúwa sọ fún mi pé, “Má ṣe bẹ̀rù u rẹ̀ torí pé mo ti fi lé e yín lọ́wọ́ pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀. Bí ẹ tí ṣe sí Ṣíhónì ọba Ámórì, tí ó jọba ní Héṣíbónì ni kí ẹ ṣe sí i.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:2 ni o tọ