Deutarónómì 3:4 BMY

4 Ní ìgbà náà ní a gba gbogbo àwọn ìlú rẹ̀. Kò sí ọ̀kankan tí a kò gbà nínú àwọn ọgọta (60) ìlú tí wọ́n ní: Gbogbo agbégbé Ágóbù, lábẹ́ ìjọba Ógù ní Báṣánì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:4 ni o tọ