Deutarónómì 3:5 BMY

5 Gbogbo ìlú wọ̀nyí ní a mọ odi gíga yíká pẹ̀lú àwọn ìlẹ̀kùn àti irin. Ọ̀pọ̀ àwọn ìlú kékèké tí a kò mọ odi yíká sì tún wà pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:5 ni o tọ