Deutarónómì 32:47 BMY

47 Wọn kì í se ọ̀rọ̀ asán fún ọ, ìyè e yín ni wọ́n. Nípa wọn ni ẹ̀yin yóò gbé pẹ́ lórí ilẹ̀ tí ẹ̀yin ń gòkè e Jọ́dánì lọ láti gbà.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:47 ni o tọ