Deutarónómì 32:49 BMY

49 “Gòkè lọ sí Ábárímù sí òkè Nébò ní Móábù, tí ó kọjú sí Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénánì ilẹ̀ tí mo ń fi fún àwọn ọmọ Isírẹ́lì, bí ìní i wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:49 ni o tọ