Deutarónómì 33:19 BMY

19 Wọn yóò pe àwọn ènìyàn sórí òkèàti níbẹ̀ wọn yóò rú ẹbọ òdodo,wọn yóò mu nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkun,nínú ìṣúra tí ó pamọ́ nínú iyanrìn.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 33

Wo Deutarónómì 33:19 ni o tọ