Deutarónómì 33:20 BMY

20 Ní ti Gádì ó wí pé:“Ìbùkún ni ẹni tí ó mú Gádì gbilẹ̀!Gádì ń gbé níbẹ̀ bí kìnnìún,ó sì fa apá ya, àní àtàrí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 33

Wo Deutarónómì 33:20 ni o tọ