Deutarónómì 33:28 BMY

28 Ísírẹ́lì nìkan yóò jòkòó ní àlàáfíà,oríṣun Jákọ́bù nìkanní ilẹ̀ ọkà àti ti ọtí wáìnì,níbi tí ọ̀run ti ń ṣẹ ìrì sílẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 33

Wo Deutarónómì 33:28 ni o tọ