Deutarónómì 33:29 BMY

29 Ìbùkún ni fún ọ, Ísírẹ́lì,ta ni ó dà bí ì rẹ,ẹni tí a gbàlà láti ọ̀dọ̀ Olúwa?Òun ni àṣà àti ìrànwọ́ rẹ̀àti idà ọlá ńlá rẹ̀.Àwọn ọ̀ta rẹ yóò tẹríba fún ọ,ìwọ yóò sì tẹ ibi gíga wọn mọ́lẹ̀.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 33

Wo Deutarónómì 33:29 ni o tọ