Deutarónómì 34:9 BMY

9 Jóṣúà ọmọ Núnì kún fún ẹ̀mí ọgbọ́n nítorí Móṣè ti gbọ́wọ́ ọ rẹ̀ lée lórí. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì fetí sí i wọ́n sì ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pa láṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Deutarónómì 34

Wo Deutarónómì 34:9 ni o tọ