Deutarónómì 34:10 BMY

10 Láti ìgbà náà kò sì sí wòlíì tí ó dìde ní Ísírẹ́lì bí i Móṣè, ẹni tí Olúwa mọ̀ lójúkojú,

Ka pipe ipin Deutarónómì 34

Wo Deutarónómì 34:10 ni o tọ