Deutarónómì 4:11 BMY

11 Ẹ̀yin súnmọ́ tòsí ẹ sì dúró ní ẹṣẹ̀ òkè náà, nígbà tí òkè náà yọná lala lọ sókè ọrun pẹ̀lú ìkúùkù ńlá, àti òkùnkùn biribiri.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:11 ni o tọ