Deutarónómì 4:12 BMY

12 Olúwa sì bá yín sọ̀rọ̀ láti àárin iná náà wá. Ẹ gbọ́ àwọn ìró ohùn, ṣùgbọ́n ẹ kò rí ẹnikẹ́ni, ohùn nìkan ni ẹ gbọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:12 ni o tọ