Deutarónómì 4:27 BMY

27 Olúwa yóò fọ́n-ọn yín ká sí àárin àwọn ènìyàn náà, àwọn díẹ̀ nínú un yín ni yóò yè láàrin orílẹ̀ èdè tí Olúwa yóò fọ́n ọn yín sí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:27 ni o tọ