Deutarónómì 4:28 BMY

28 Ẹ ó sì máa sin Ọlọ́run tí àwọn ènìyàn fi ọwọ́ ṣe: tí wọ́n fi igi àti òkúta ṣe, èyí tí kò le ríran, gbọ́rọ̀, jẹun tàbí gbọ́ òórùn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:28 ni o tọ