Deutarónómì 4:36 BMY

36 Ó jẹ́ kí ẹ gbọ́ ohùn rẹ̀ láti ọ̀run wá, láti kọ́ ọ yín. Ní aye, ó fi iná ńlá rẹ̀ hàn yín, ẹ sì gbọ́ ohùn rẹ̀ láti àárin iná wá,

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:36 ni o tọ