Deutarónómì 4:37 BMY

37 torí pé ó fẹ́ràn àwọn baba ńlá yín, ó sì yan àwọn ọmọ wọn ní ipò lẹ́yìn wọn. Nípa ìwà láàyè àti nípa agbára ńlá rẹ̀ ni ó fi mú un yín kúrò ní Éjíbítì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:37 ni o tọ