Deutarónómì 4:38 BMY

38 Láti lé àwọn orílẹ̀ èdè tí ó tóbi tí ó sì lágbára níwájú yín; láti le è mú un yín wá sí ilẹ̀ wọn kí ẹ lè jogún rẹ̀ bí ó ti rí lónìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:38 ni o tọ