Deutarónómì 4:39 BMY

39 Ẹ gbà kí ẹ sì fi sọ́kàn lónìí pé Olúwa ni Ọlọ́run lókè ọ̀run lọ́hùn ún àti ní ilẹ̀ ní ìṣàlẹ̀ níhìn ín. Kò sí òmíràn mọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:39 ni o tọ