Deutarónómì 4:5 BMY

5 Ẹ kíyèsí i, mo ti kọ́ ọ yín ní àwọn òfin àti àṣẹ bí Olúwa Ọlọ́run-ùn mi ti pàṣẹ fún mi, kí ẹ ba à le tẹ̀lé wọn ní ilẹ̀ náà tí ẹ ń lọ láti ní ní ìní.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:5 ni o tọ