Deutarónómì 4:6 BMY

6 Ẹ máa kíyèsí wọn dáradára. Èyí ni yóò fi ọgbọ́n àti òye yín han àwọn orílẹ̀ èdè. Àwọn tí wọn yóò gbọ́ nípa àwọn ìlànà wọ̀nyí, tí wọn yóò sì máa wí pé, “Dájúdájú, orílẹ̀ èdè ńlá yìí kún fún ọgbọ́n àti òye.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:6 ni o tọ