Deutarónómì 7:10 BMY

10 Ṣùgbọ́nàwọn tí ó kórìíra rẹ̀ ni yóò san ẹ̀san fún ní gbangba nípa pípa wọ́n run;kì yóò sì jáfara láti san ẹ̀san fún àwọn tí ó kórìíra rẹ̀ ní gbangba.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:10 ni o tọ