Deutarónómì 7:11 BMY

11 Nítorí náà ẹ kíyési láti máa tẹ̀lé àwọn àṣẹ, ìlànà àti òfin tí mo fun un yín lónìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:11 ni o tọ