Deutarónómì 7:14 BMY

14 A ó bùkún un yín ju gbogbo ènìyàn lọ, kò sí ẹni tí yóò yàgàn nínú ọkùnrin tàbí obìnrin yín, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ọ̀kan nínú àwọn ohun ọ̀sìn in yín tí yóò wà láìlọ́mọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:14 ni o tọ