Deutarónómì 7:15 BMY

15 Olúwa yóò pa ọ́ mọ́ kúrò nínú àrùn gbogbo, kì yóò jẹ́ kí èyíkéyìí àrùn búburú tí ẹ mọ̀ ní Éjíbítì wá sára yín, ṣùgbọ́n yóò fi wọ́n lé ara gbogbo àwọn tí ó kórìíra yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:15 ni o tọ