Deutarónómì 7:18 BMY

18 Ṣùgbọ́n ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn: Ẹ rántí dáradára ohun tí Olúwa Ọlọ́run yín ṣe sí Fáráò àti gbogbo Éjíbítì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:18 ni o tọ