Deutarónómì 7:24 BMY

24 Yóò fi àwọn ọba wọn lé e yín lọ́wọ́, ẹ̀yin ó sì pa orúkọ wọn rẹ́ lábẹ́ ọ̀run. Kò sí ẹni tí yóò lè dojú ìjà kọ yín títí tí ẹ ó fi pa wọ́n run.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:24 ni o tọ