Deutarónómì 7:25 BMY

25 Dá iná sun àwọn ère òrìṣà wọn, ẹ má ṣe ṣe ojúkòkòrò sí fàdákà tàbí wúrà tí ó wà lára wọn. Ẹ má ṣe mú un fún ara yín, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ yóò jẹ́ ìdẹkùn fún un yín, torí pé ìríra ni sí Olúwa Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:25 ni o tọ