Deutarónómì 7:26 BMY

26 Ẹ má ṣe mú ohun ìríra wá sí ilé yín, kí ìwọ má bàá di ẹni ìparun bí i rẹ̀. Ẹ kóríra rẹ̀ kí ẹ sì kàá sí ìríra pátapáta, torí pé a yà á sọ́tọ̀ fún ìparun ni.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:26 ni o tọ