Deutarónómì 8:1 BMY

1 Ẹ kíyèsí láti máa tẹ̀lé gbogbo àṣẹ tí mo fún un yín lónìí, kí ẹ báà le yè kí ẹ sì pọ̀ sí i wọ ilẹ̀ náà, kí ẹ sì le gba ilẹ̀ náà, tí Olúwa fìbúra ṣèlérí fún àwọn baba ńlá a yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:1 ni o tọ