Deutarónómì 8:2 BMY

2 Ẹ rántí bí Olúwa Ọlọ́run yín ti tọ́ ọ yín sọ́nà ní gbogbo ọ̀nà ní ihà fún ogójì ọdún wọ̀nyí láti tẹ orí i yín ba àti láti dán an yín wò kí ó báà le mọ bí ọkàn yín ti rí, bóyá ẹ ó pa òfin rẹ̀ mọ́ tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:2 ni o tọ