Deutarónómì 8:20 BMY

20 Bí àwọn orílẹ̀ èdè tí Olúwa parun níwájú u yín, bákan náà ni ẹ ó parun, torí pé ẹ kò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run yín lẹ́nu.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:20 ni o tọ