Deutarónómì 9:1 BMY

1 Gbọ́, ìwọ Ísírẹ́lì. Báyìí, ẹ ti gbáradì látí la Jọ́dánì kọjá, láti lọ gba ilẹ̀ àwọn orílẹ̀ èdè tí wọ́n tóbi, tí wọ́n sì lágbára jù yín lọ, tí wọ́n ní àwọn ìlú ńláńlá, tí odi wọn kan ọ̀run.

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:1 ni o tọ