Deutarónómì 8:5 BMY

5 Ẹ mọ̀ ní ọkàn an yín pé, bí baba ti ń kọ́ ọmọ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni Olúwa Ọlọ́run yín ń kọ́ ọ yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:5 ni o tọ