Deutarónómì 9:10 BMY

10 Olúwa fún mi ní òkúta méjì tí a fi ìka Ọlọ́run kọ. Lórí wọn ni a kọ àwọn òfin tí Ọlọ́run sọ fún un yín lórí òkè láàrin iná, ní ọjọ́ ìpéjọpọ̀ sí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:10 ni o tọ