Deutarónómì 9:9 BMY

9 Nígbà tí mo gòkè lọ láti lọ gba sílétì òkúta, sílétì májẹ̀mú ti Olúwa ti bá a yín dá. Ogójì ọ̀sán àti òru ni mo fi wà lórí òkè náà, èmi kò fẹnu kan oúnjẹ bẹ́ẹ̀ ni ń kò mumi.

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:9 ni o tọ