Deutarónómì 9:26 BMY

26 Mo gbàdúrà sí Olúwa wí pé, “Olúwa Olódùmarè, má ṣe run àwọn ènìyàn rẹ, àní ogún rẹ tí o ti ràpadà, nípa agbára rẹ tí o sì fi agbára ńlá mú wọn jáde láti Éjíbítì wá.

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:26 ni o tọ