Deutarónómì 9:27 BMY

27 Rántí àwọn ìránṣẹ́ rẹ Ábúráhámù, Ísáákì, àti Jákọ́bù. Fojú fo orí kunkun àwọn ènìyàn yìí, pẹ̀lú ìwà búburú àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:27 ni o tọ