11 Láti ọ̀dọ̀ Bẹ́ńjámínì, Ábídánì ọmọ Gídíónì;
12 Láti ọ̀dọ̀ Dánì, Áhíésérì ọmọ Ámísádáì;
13 Láti ọ̀dọ̀ Áṣérì, Págíélì ọmọ Ókíránì;
14 Láti ọ̀dọ̀ Gáádì, Élíásàfu ọmọ Déúélì;
15 Láti ọ̀dọ̀ Náfítalì, Áhírà ọmọ Énánì.”
16 Àwọn wọ̀nyìí ni wọ́n yàn nínú àwùjọ ènìyàn, olórí àwọn ẹ̀yà baba wọn. Àwọn ni olórí àwọn ẹbí Ísírẹ́lì.
17 Mósè àti Árónì mú àwọn ènìyàn tí a dárúkọ wọ̀nyí