Nọ́ḿbà 11:32 BMY

32 Ní gbogbo ọjọ́ náà àti òru, títí dé ọjọ́ kejì ni àwọn ènìyàn fi ń kó àparò yìí: Ẹni tó kó kéré jù lọ kó ìwọ̀n hómérì mẹ́wáà, wọ́n sì sà wọ́n sílẹ̀ fún ara wọn yí gbogbo ibùdó.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:32 ni o tọ