Nọ́ḿbà 11:33 BMY

33 Ṣùgbọ́n nígbà tí ẹran náà sì wà láàrin eyín wọn, kó tó di pé wọ́n jẹ ẹ́, ìbínú Olúwa sì ru sí àwọn ènìyàn, ó sì pa wọ́n pẹ̀lú àjàkálẹ̀-àrùn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:33 ni o tọ