Nọ́ḿbà 11:34 BMY

34 Torí èyí ni wọ́n ṣe pe ibẹ̀ ní Kíbírótì Hátafà nítorí pé níbẹ̀ ni wọ́n gbé sìnkú àwọn ènìyàn tó ní ọ̀kánjúà oúnjẹ sí.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:34 ni o tọ