Nọ́ḿbà 14:31 BMY

31 Ṣùgbọ́n ní ti àwọn ọmọ yín tí ẹ wí pé wọn ó di ìjẹ, àwọn ni n ó mú dé bẹ̀ láti gbádùn ilẹ̀ tí ẹ kọ̀ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:31 ni o tọ