Nọ́ḿbà 14:43 BMY

43 Nítorí pé àwọn ará Ámélékì àti àwọn ará Kénánì yóò kojú yín níbẹ̀. Nítorí pé Ẹ ti yà kúrò ní ọ̀nà Olúwa, Olúwa kò sì ní í wà pẹ̀lú yín.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:43 ni o tọ