Nọ́ḿbà 14:44 BMY

44 Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀, pẹ̀lú àìfarabalẹ̀ wọn, wọ́n gòkè lọ sórí òkè náà, láì jẹ́ pé àpótí ẹ̀rí májẹ̀mú Olúwa tàbí Mósè kúrò nínú ibùdó.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:44 ni o tọ