Nọ́ḿbà 16:27 BMY

27 Àwọn ènìyàn sì sún kúrò ní àgọ́ Kórà, Dátanì àti Ábírámù. Dátanì àti Ábírámù jáde, àwọn ìyàwó wọn àti àwọn ọmọ wọn sì dúró sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:27 ni o tọ