Nọ́ḿbà 16:37 BMY

37 “Sọ fún Élíásárì ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà, pé kí ó mú àwọn àwo tùràrí jáde kúrò nínú iná nítorí pé wọ́n jẹ́ mímọ́, kí ó sì tan iná náà káàkiri síbi tó jìnnà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:37 ni o tọ